Jamisi by Danny S, Lyrics

Danny S – Jamisi

(Chorus)
Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko, Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko
Jamisi bo’she nlo, ki lo n d’owo, fi mi si bo she’nlo, ki lo n pa’wo
Jamisi bo’she nlo, oju ti di, fi mi si bo she’nlo, emi gan fe gbowo

(Verse)
Omo to ba dun, ila ku lala, a brukutu maye ayaku yaya
Lebrete mato mato, anoti oleto le o mato, Oloun gbo

To ba fun e ni pick 2, omo ope gba pick 2, a sun burn ati harmattan, ki la ati harmattan
Won l’oye ki’n pa ara igbeti, eni a bi so’ye, lo’ye n pa
Iku pa mi ti, arun shey mi ti, anybody to ba shey yama yama, eti won bota

(Chorus)
Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko, Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko
Jamisi bo’she nlo, ki lo n d’owo, fi mi si bo she’nlo, ki lo n pa’wo

Jamisi bo’she nlo, oju ti di, fi mi si bo she’nlo, emi gan fe gbowo

(Outro)
Iku pa mi ti, arun shey mi ti, anybody to ba shey yama yama, eti won bota
Meji loyan, okan loko, what do I know, o ta koko
All the way from iju, awon omo shaolin temple, all the way from ilu shaku shaku, awon omo ijoba gurumangusu
Awa o kin shey omo jaku jaku

Post a Comment

أحدث أقدم